Cisreports

HOME | GOSPEL | AMERICAN | NIGERIAN | SOUTH AFRICAN | HIGHLIFE | REGGAETope Alabi – Eyin Oluwa Halleluyah

Posted by: || Categories: music

Get this song from Tope Alabi which she titled Eyin Oluwa Halleluyah

Use this link below to Stream and download Eyin Oluwa Halleluyah by Tope Alabi

Download Eyin Oluwa Halleluyah by Tope Alabi

Lyrics Of Eyin Oluwa Halleluyah by Tope Alabi

Verse 1:
Eje ka f’ope fun o e
Iwa Olorun ni iyin to po
Eru ipa a re po o e
Bela nu re duro o lailai

Chorus:
Eyin o Oluwa o Halleluyah
Egbe e ga o o o o o Halleluyah
Eyin Oluwa o Halleluyah
O n logaju o o o o Halleluyah

Verse 2:
Yin oun to fogbon da orun
Yin oun to lewa ninu ogo
Yin oun ti kerubu sarafu korin si o
Oun re ru awon omi okun

Verse 3:
Nitori tori majemu ati pinlese
Nitori tori dodo re ti kosaki
Nitori irele ati fe re siwa
Nitori agbara re topo pupo

Verse 4:
Yin in tinu tinu u re
Yin in gbogbo to okan tara a
Yin in bawon torun un o o o
Oun loni ife e waju lo

Download Mp3 Here


0 Comments

You must be logged in to post a comment.

« | »