Cisreports

HOME | GOSPEL | AMERICAN | NIGERIAN | SOUTH AFRICAN | HIGHLIFE | REGGAETope Alabi – Loro Lero Ati Nise

Posted by: || Categories: music

Get this song from Tope Alabi which she titled Loro Lero Ati Nise

Use this link below to Stream and download Loro Lero Ati Nise by Tope Alabi

Download Loro Lero Ati Nise by Tope Alabi

Lyrics Of Loro Lero Ati Nise by Tope Alabi

Verse 1:
Emi ofe o oluwa, agbara a’tapata
Iwo ni igbalami, ilu olodi mi
Ile iso mi giga, towo ota kole kan
ofami jade wa lati inu omi nla
Titi lemi o fe loro lero nise

Chorus:
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise
Loro lero ati nise

Verse 2:
Emi o fe o oluwa, Iwo ni iranwo mi
Emi o gbekele e o, igbala owo’tun re
Iranwo re yo mumi d’ro sinsin
Awon elomiran gbeke won le keke ogun
Sugbon emi gbekele loro lero nise

Verse 3:
Emi o mayo s’oluwa, oba ati ase mi
Fi’bukun fun oluwa, anu re duro titi
Ofi ade demi o komi lona re
Ola at’ojo gigun lo jogun fun mi
Ope mi yo po loro lero nise.

Download Mp3 Here


0 Comments

You must be logged in to post a comment.

« | »